About Me

My photo
I AM WHO I AM. I AM WHO I'VE BEEN PUT ON THIS EARTH TO BECOME. I AM WHO I WANT TO BE. I AM ME.

Tuesday, November 17, 2009

Gving thanks to God in Yoruba. (One of The Nigerian Language)

Inu mi dun wipe mo ni Oluwa le gbe mi!
Ni gbati mi o ba ni enikankan lati ba soro, Oluwa wa pelu mi.

Mo kan so wipe Ose Olorun. Iwo ni kan ni mo gbo ju le. enikan ti mo gberan le.
Oba mi, Ore mi. Baba mi, Mama mi.

Kaaaa bi ye si Oluwa.
Ose o.